Yoruba(Nigeria)Llbrary

Yoruba(Nigeria)Llbrary

Book Coverdownload pdf book


Book Coverdownload pdf book


Book Coverdownload pdf book


Book Coverdownload pdf book


Book Coverdownload pdf book


Book Coverdownload pdf book

Ifọrọwọrọ Laarin Musulumi Ati Kristiani

Title:Ifọrọwọrọ Laarin Musulumi Ati Kristiani
Language:Yoruba
Short Discription:Iwe yii je iforowero laarin eni ti o se e ati awon alagba kan ninu esin Kristiani
1.

Ifọrọwọrọ Laarin Musulumi Ati Kristiani
438.3 KB
Open: Ifọrọwọrọ Laarin Musulumi Ati Kristiani.pdf

Awọn Obirin Ninu Islam

Title:Awọn Obirin Ninu Islam
Language:Yoruba
1.

Awọn Obirin Ninu Islam
766.8 KB
Open: Awọn Obirin Ninu Islam.pdf

OOrun didun igi ododo ti orewa nipa ajulo awon iya awon olugbagbo ododo

Title:OOrun didun igi ododo ti orewa nipa ajulo awon iya awon olugbagbo ododo
Language:Yoruba
1.

OOrun didun igi ododo ti orewa nipa ajulo awon iya awon olugbagbo ododo
470.3 KB
Open: OOrun didun igi ododo ti orewa nipa ajulo awon iya awon olugbagbo ododo.pdf
2.

OOrun didun igi ododo ti orewa nipa ajulo awon iya awon olugbagbo ododo
1.6 MB
Open: OOrun didun igi ododo ti orewa nipa ajulo awon iya awon olugbagbo ododo.doc

Itumọ Idamẹwaa Ikẹyin Ninu Al-Quraan Alapọnle

Title:Itumọ Idamẹwaa Ikẹyin Ninu Al-Quraan Alapọnle
Language:Yoruba
Short Discription:Itumọ Idamẹwaa Ikẹyin Ninu Al-Quraan Alapọnle.
1.

For Print
132.1 MB
Open: For Print.pdf
2.

For web
13.6 MB
Open: For web.pdf

Awọn itaniji lori awọn idajọ ti o jẹ adayanri fun awọn olugbagbọ-ododo ni obinrin

Title:Awọn itaniji lori awọn idajọ ti o jẹ adayanri fun awọn olugbagbọ-ododo ni obinrin
Language:Yoruba
Translation:Sharafuddeen Gbadebọ Raji
1.

Awọn itaniji lori awọn idajọ ti o jẹ adayanri fun awọn olugbagbọ-ododo ni obinrin
5.3 MB
Open: Awọn itaniji lori awọn idajọ ti o jẹ adayanri fun awọn olugbagbọ-ododo ni obinrin.pdf

IWE AT-TAWHEED ’’SISE ỌLỌHUN ỌBA NI ỌKAN SOSO NINU IJỌSIN

Title:IWE AT-TAWHEED ’’SISE ỌLỌHUN ỌBA NI ỌKAN SOSO NINU IJỌSIN
Language:Yoruba
Authorship:Muhammad Ibn sulaiman At-Tameemi
Translation:Sharafuddeen Gbadebọ Raji
1.

IWE AT-TAWHEED ”SISE ỌLỌHUN ỌBA NI ỌKAN SOSO NINU IJỌSIN”
5.8 MB
Open: IWE AT-TAWHEED ''SISE ỌLỌHUN ỌBA NI ỌKAN SOSO NINU IJỌSIN".pdf

Adisọkan Awọn Ahlus-Sunnah Wal-Jamaa’ah

Title:Adisọkan Awọn Ahlus-Sunnah Wal-Jamaa’ah
Language:Yoruba
Translation:Sharafuddeen Gbadebọ Raji
1.

Adisọkan Awọn Ahlus-Sunnah Wal-Jamaa’ah
900.6 KB
Open: Adisọkan Awọn Ahlus-Sunnah Wal-Jamaa'ah.pdf

ALAYE BI IRUN ANABI KI IKẸ ATI ỌLA ỌLỌHUN O MAA BA A TI RI

Title:ALAYE BI IRUN ANABI KI IKẸ ATI ỌLA ỌLỌHUN O MAA BA A TI RI
Language:Yoruba
Translation:Sharafuddeen Gbadebọ Raji
1.

ALAYE BI IRUN ANABI KI IKẸ ATI ỌLA ỌLỌHUN O MAA BA A TI RI
726.9 KB
Open: ALAYE BI IRUN ANABI KI IKẸ ATI ỌLA ỌLỌHUN O MAA BA A TI RI.pdf

Islam Awọn ipilẹ rẹ ati awọn ipilẹsẹ ẹkọ rẹ

itle:Islam Awọn ipilẹ rẹ ati awọn ipilẹsẹ ẹkọ rẹ
Language:Yoruba
Translation:Sharafuddeen Gbadebọ Raji
1.

Islam Awọn ipilẹ rẹ ati awọn ipilẹsẹ ẹkọ rẹ
935.4 KB
Open: Islam Awọn ipilẹ rẹ ati awọn ipilẹsẹ ẹkọ rẹ.pdf
2.

Islam Awọn ipilẹ rẹ ati awọn ipilẹsẹ ẹkọ rẹ
2.3 MB
Open: Islam Awọn ipilẹ rẹ ati awọn ipilẹsẹ ẹkọ rẹ.doc

Awon leta ti o wa fun awon Alhaji ati awon oni Umrah

Title:Awon leta ti o wa fun awon Alhaji ati awon oni Umrah
Language:Yoruba
1.

Awon leta ti o wa fun awon Alhaji ati awon oni Umrah
394.5 KB
Open: Awon leta ti o wa fun awon Alhaji ati awon oni Umrah.pdf
2.

Awon leta ti o wa fun awon Alhaji ati awon oni Umrah
1.3 MB
Open: Awon leta ti o wa fun awon Alhaji ati awon oni Umrah.doc

Àwọn Origun Ẹsin Islãm

Title:Àwọn Origun Ẹsin Islãm
Language:Yoruba
Publisher:www.iu.edu.sa – Ilé-ẹkọ giga Islãm ni Mọdinat
Short Discription:Àwọn Origun Ẹsin Islãm
1.

Àwọn Origun Ẹsin Islãm
689 KB
Open: Àwọn Origun Ẹsin Islãm.pdf
2.

Àwọn Origun Ẹsin Islãm
2.7 MB
Open: Àwọn Origun Ẹsin Islãm.doc

AWỌN ADUA TI WỌN JẸ AABO FUN MUSULUMI LATI INU AL-QUR’AANI ATI SUNNA

Title:AWỌN ADUA TI WỌN JẸ AABO FUN MUSULUMI LATI INU AL-QUR’AANI ATI SUNNA
Language:Yoruba
Authorship:Sa’id Bn Ali Bn Wahf Al-Qahtaani
Translation:Sharafuddeen Gbadebọ Raji
1.

AWỌN ADUA TI WỌN JẸ AABO FUN MUSULUMI LATI INU AL-QUR’AANI ATI SUNNA
5.3 MB
Open: AWỌN ADUA TI WỌN JẸ AABO FUN MUSULUMI LATI INU AL-QUR’AANI ATI SUNNA.pdf

AL QUR’AN ALAPỌNLE PẸLU ITUMỌ RẸ NI EDE YORUBA

itle:AL QUR’AN ALAPỌNLE PẸLU ITUMỌ RẸ NI EDE YORUBA
Language:Yoruba
Publisher:lie itẹ AI Qur’an Alapọnle, ti o jẹ ti ọba Fahd
1.

AL QUR’AN ALAPỌNLE PẸLU ITUMỌ RẸ NI EDE YORUBA
23 MB
Open: AL QUR'AN ALAPỌNLE PẸLU ITUMỌ RẸ NI EDE YORUBA.pdf

Awọn ipilẹ mẹta ẹsin islam ati awọn ẹri wọn

itle:Awọn ipilẹ mẹta ẹsin islam ati awọn ẹri wọn
Language:Yoruba
Authorship:Muhammad Ibn sulaiman At-Tameemi
Translation:Sharafuddeen Gbadebọ Raji
Publisher:www.iu.edu.sa – Ilé-ẹkọ giga Islãm ni Mọdinat
1.

Awọn ipilẹ mẹta ẹsin islam ati awọn ẹri wọn
200.3 KB
Open: Awọn ipilẹ mẹta ẹsin islam ati awọn ẹri wọn.pdf
2.

Awọn ipilẹ mẹta ẹsin islam ati awọn ẹri wọn
1.7 MB
Open: Awọn ipilẹ mẹta ẹsin islam ati awọn ẹri wọn.doc

Awọn origun igbagbọ-ododo“Al-Iimaan”

Title:Awọn origun igbagbọ-ododo“Al-Iimaan”
Language:Yoruba
Translation:Sharafuddeen Gbadebọ Raji
Publisher:www.iu.edu.sa – Ilé-ẹkọ giga Islãm ni Mọdinat
1.

Awọn origun igbagbọ-ododo“Al-Iimaan”
627.8 KB
Open: Awọn origun igbagbọ-ododo“Al-Iimaan”.pdf
2.

Awọn origun igbagbọ-ododo“Al-Iimaan”
2.6 MB
Open: Awọn origun igbagbọ-ododo“Al-Iimaan”.doc

Kinni o nje Sunna ?

Title:Kinni o nje Sunna ?
Language:Yoruba
The Lecturer:Rafiu Adisa Bello
Short Discription:Ibanisoro yi so nipa itumo sunna, o si je ki a mo igba ti awon Musulumi bere si pe awon kan ni oni sunna. Ni ipari alaye tun waye lori awon apeere ti a fi maa nda awon oni sunna mo; nitoripe opolopo naa ni won maa npe ara won ni oni sunna ti won si jinna si i.
1.

Kinni o nje Sunna ?
71.1 MB
Listen: Kinni o nje Sunna ?.mp3

Awon Eko ti o nbe nibi Ipepe Sheikh Muhammad ibn Abdul-wahab

Title:Awon Eko ti o nbe nibi Ipepe Sheikh Muhammad ibn Abdul-wahab
Language:Yoruba
The Lecturer:Rafiu Adisa Bello
Short Discription:Alaye waye ninu ibanisoro yi nipa awon eko ti o nbe nibi ipepe Sheikh Muhammad ibn Abdul-wahab. Oniwaasi so nipa bi o se je wipe soki ohun ti ipepe Sheikh da le lori ni mimo Olohun ni okan soso ati dida oju ko O ni Oun nikan nibi awon ijosin.
1.

Awon Eko ti o nbe nibi Ipepe Sheikh Muhammad ibn Abdul-wahab
70.8 MB
Listen: Awon Eko ti o nbe nibi Ipepe Sheikh Muhammad ibn Abdul-wahab.mp3

Awon Janmoo Islam: Oore ti o nbe lara won ati ibi ti won ku si

Title:Awon Janmoo Islam: Oore ti o nbe lara won ati ibi ti won ku si
Language:Yoruba
The Lecturer:Abdur-rosheed Ballo Oluajo
Reviewing:Rafiu Adisa Bello
Short Discription:Awon janmoo Islam ti o wa ni awujo ni anfaani pupo, awon ni won nse itoju awon omo Musulumi ti won ko je ki opolopo won ti sina tabi di keferi, won maa nse alaye esin fun awon omode ati odo ati agbalagba, bibe won ni awujo si je amin isokan fun awa Musulumi. Sugbon apa kan ninu awon janmoo yi ni awon aleebu kookan gege bii ki a gba wipe olori janmoo ko le se asise ati wipe janmoo ti a ba wa ninu re nikan ni ona sunna ti o dara julo, irufe awon nkan yii ni olubanisoro menu ba ninu waasi yi.
1.

Awon Janmoo Islam: Oore ti o nbe lara won ati ibi ti won ku si
98.7 MB
Listen: Awon Janmoo Islam: Oore ti o nbe lara won ati ibi ti won ku si.mp3

Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna

Title:Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna
Language:Yoruba
The Lecturer:Abdur-rahman Adunola Abdul-wahab
Reviewing:Rafiu Adisa Bello
Short Discription:Ibanisoro yi da lori oro nipa adiokan Imam Abu Haniifa, biotile je wipe olubanisoro menu ba adiokan awon Imaamu mereerin. Ohun ti o si se okunfa eleyi ni bi apa kan ninu awon alaimokan ni awujo se npe Imaam Abu Haniifa ni keeferi nitori awon iruju kan ti o nbe fun won nipa adiokan re. Eleyi ni oniwaasi yi se alaye re ni ekunrere, ki Olohun fi se awon Musulumi ni anfaani.
1.

Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna
156.3 MB
Listen: Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna.mp3

Idajo Islam lori Orin kiko ati Gbigbo

Title:Idajo Islam lori Orin kiko ati Gbigbo
Language:Yoruba
The Lecturer:Isa Akindele Solahudeen
Reviewing:Rafiu Adisa Bello
Short Discription:Waasi yi so nipa idajo Islam lori orin kiko ati gbigbo. Oniwaasi mu awon eri ti o po wa lati inu Al-kurani ati hadiisi lori bi orin gbigbo ati kiko se je eewo ninu Islam. Bakannaa ni oro waye ninu waasi yi lori awon aburu repete ti o wa nibi gbigbo orin ati kiko.
1.

Idajo Islam lori Orin kiko ati Gbigbo
44.2 MB
Listen: Idajo Islam lori Orin kiko ati Gbigbo.mp3

Awon Nkan Ti O leto Fun Musulumi Lati Maa Fi Se Iwosan

Title:Awon Nkan Ti O leto Fun Musulumi Lati Maa Fi Se Iwosan
Language:Yoruba
The Lecturer:Rafiu Adisa Bello
Short Discription:Alaye ni ekunrere wa ninu ibanisoro yi lori awon nkan ti o leto fun Musulumi lati maa lo fun idena arun ati lati wa iwosan nigbati arun ba n se e. Bakannaa ni oro tun waye lori awon oogun ti o leto fun Musulumi lati lo ti o si so awon nkan ti esin se ni eewo fun Musumi.
1.

Awon Nkan Ti O leto Fun Musulumi Lati Maa Fi Se Iwosan
61.6 MB
Listen: Awon Nkan Ti O leto Fun Musulumi Lati Maa Fi Se Iwosan.mp3

Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna

 

itle:Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna
Language:Yoruba
The Lecturer:Rafiu Adisa Bello
Short Discription:Ibanisoro yi so ni ekunrere nipa itumo adadaale ninu esin pelu awon eri lati inu Al-kurani ati Sunna Ojise. O si se alaye ewu ti o wa nibi ki musulumi maa tele awon ti won ba n da adadaale ninu esin. Ni afikun, o tun se alaye awon majemu ti a fi maa nmo adadaale nitori awon iruju ti o wa fun awon Musulumi kan lori re.
1.

Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna
99 MB
Listen: Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna.mp3

AL QUR’AN ALAPỌNLE PẸLU ITUMỌ RẸ NI EDE YORUBA [part 30 ]

Title:AL QUR’AN ALAPỌNLE PẸLU ITUMỌ RẸ NI EDE YORUBA [part 30 ]
Language:Yoruba
Publisher:lie itẹ AI Qur’an Alapọnle, ti o jẹ ti ọba Fahd
1.

Translation of surat al-Fatihah’s and Ammah Part surats’ meanings
25.9 MB
Listen: Translation of surat al-Fatihah's and Ammah Part surats' meanings.mp3

The Rites Of Hajj And Umra(Piligramme And Minor Piligramme)

Title:The Rites Of Hajj And Umra(Piligramme And Minor Piligramme)
Language:Yoruba
Publisher:لجنة الدعوة والتعليم بالمدينة المنورة
1.

The Rites Of Hajj And Umra(Piligramme And Minor Piligramme)
16.1 MB
Listen: The Rites Of Hajj And Umra(Piligramme And Minor Piligramme).mp3

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s